-
Jeremáyà 9:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Sọ pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
“Òkú àwọn èèyàn á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀
Àti bí ìtí ọkà tí olùkórè ṣẹ̀ṣẹ̀ gé sílẹ̀,
Tí ẹnì kankan kò ní kó jọ.”’”+
-