Ìdárò 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà ti ti gbogbo àwọn alágbára tó wà láàárín mi sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan.+ Ó ti pe àwọn èèyàn jọ sí mi kí wọ́n lè pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi.+ Jèhófà ti tẹ wúńdíá ọmọbìnrin Júdà bí àjàrà níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì.+
15 Jèhófà ti ti gbogbo àwọn alágbára tó wà láàárín mi sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan.+ Ó ti pe àwọn èèyàn jọ sí mi kí wọ́n lè pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi.+ Jèhófà ti tẹ wúńdíá ọmọbìnrin Júdà bí àjàrà níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì.+