-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 23:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 “Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Èmi yóò gbé àwọn ọmọ ogun dìde láti bá wọn jà, kí ìbẹ̀rù lè bò wọ́n, kí wọ́n sì kó wọn lẹ́rù.+
-