Jeremáyà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dúró ní oríta, kí ẹ sì wò. Ẹ béèrè àwọn ọ̀nà àtijọ́,Ẹ béèrè ibi tí ọ̀nà tó dára wà, kí ẹ sì máa rìn ín,+Kí ẹ* lè rí ìsinmi.” Ṣùgbọ́n wọ́n sọ pé: “A ò ní rin ọ̀nà náà.”+
16 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dúró ní oríta, kí ẹ sì wò. Ẹ béèrè àwọn ọ̀nà àtijọ́,Ẹ béèrè ibi tí ọ̀nà tó dára wà, kí ẹ sì máa rìn ín,+Kí ẹ* lè rí ìsinmi.” Ṣùgbọ́n wọ́n sọ pé: “A ò ní rin ọ̀nà náà.”+