-
Jóòbù 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Kí ọjọ́ tí wọ́n bí mi + ṣègbé,
Àti òru tí ẹnì kan sọ pé: ‘Wọ́n ti lóyún ọkùnrin kan!’
-
-
Jeremáyà 15:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ìwọ ìyá mi, mo gbé nítorí pé o bí mi,+
Ọkùnrin tí gbogbo ilẹ̀ náà ń bá jà, tí wọ́n sì ń bá fa wàhálà.
Mi ò yáni lówó, bẹ́ẹ̀ ni mi ò yáwó lọ́wọ́ ẹnì kankan;
Àmọ́ gbogbo wọn ń gbé mi ṣépè.
-