Jeremáyà 39:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+ Míkà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí yín,Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.*+
8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+
12 Nítorí yín,Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.*+