2 Kíróníkà 29:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí àwọn bàbá wa ti hùwà àìṣòótọ́, wọ́n sì ti ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Wọ́n fi í sílẹ̀, wọ́n yí ojú wọn kúrò níbi àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, wọ́n sì kẹ̀yìn sí i.+ Jeremáyà 32:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Wọ́n ń kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n máa yíjú sí mi; + bí mo tiẹ̀ ń kọ́ wọn léraléra,* kò sí ìkankan nínú wọn tó fetí sílẹ̀, tó sì gba ìbáwí.+
6 Nítorí àwọn bàbá wa ti hùwà àìṣòótọ́, wọ́n sì ti ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Wọ́n fi í sílẹ̀, wọ́n yí ojú wọn kúrò níbi àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, wọ́n sì kẹ̀yìn sí i.+
33 Wọ́n ń kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n máa yíjú sí mi; + bí mo tiẹ̀ ń kọ́ wọn léraléra,* kò sí ìkankan nínú wọn tó fetí sílẹ̀, tó sì gba ìbáwí.+