-
Jeremáyà 25:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jèhófà sì rán gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wòlíì sí yín, léraléra ló ń rán wọn,* ṣùgbọ́n ẹ kò fetí sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò dẹ etí yín sílẹ̀ láti gbọ́.+ 5 Wọ́n ń sọ pé, ‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ yí pa dà, kí kálukú yín kúrò nínú ọ̀nà búburú rẹ̀ àti kúrò nínú ìwà ibi rẹ̀,+ kí ẹ lè máa gbé títí láé lórí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fún ẹ̀yin àti àwọn baba ńlá yín tipẹ́tipẹ́.
-