-
Ẹ́sírà 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ta ni nínú yín tó jẹ́ èèyàn rẹ̀? Kí Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀, kí ó lọ sí Jerúsálẹ́mù tó wà ní Júdà, kí ó sì tún ilé Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì kọ́, òun ni Ọlọ́run tòótọ́, tí ilé rẹ̀ wà ní Jerúsálẹ́mù.*
-
-
Jeremáyà 12:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ lẹ́yìn tí mo bá fà wọ́n tu, màá tún ṣàánú wọn, màá sì mú kálukú wọn pa dà sí ogún rẹ̀ àti sí ilẹ̀ rẹ̀.”
-
-
Ìsíkíẹ́lì 36:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Èmi yóò kó yín látinú àwọn orílẹ̀-èdè, màá pa dà kó yín jọ láti gbogbo ilẹ̀, màá sì mú yín wá sórí ilẹ̀ yín.+
-