Léfítíkù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run. Jeremáyà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+
33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.
16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+