Jeremáyà 18:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Fiyè sí mi, Jèhófà,Sì fetí sí ohun tí àwọn alátakò mi ń sọ. 20 Ṣé ó yẹ kéèyàn fi ibi san ire? Nítorí wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún ẹ̀mí* mi.+ Rántí bí mo ṣe dúró níwájú rẹ láti sọ ohun tó dáa nípa wọn,Kí o lè yí ìbínú rẹ kúrò lórí wọn.
19 Fiyè sí mi, Jèhófà,Sì fetí sí ohun tí àwọn alátakò mi ń sọ. 20 Ṣé ó yẹ kéèyàn fi ibi san ire? Nítorí wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún ẹ̀mí* mi.+ Rántí bí mo ṣe dúró níwájú rẹ láti sọ ohun tó dáa nípa wọn,Kí o lè yí ìbínú rẹ kúrò lórí wọn.