2 Torí náà, ọba pe àwọn ará Gíbíónì,+ ó sì bá wọn sọ̀rọ̀. (Àwọn ará Gíbíónì kì í ṣe ara àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n jẹ́ àwọn Ámórì+ tó ṣẹ́ kù, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ti búra pé àwọn máa dá wọn sí,+ àmọ́ Sọ́ọ̀lù wá ọ̀nà títí ó fi pa wọ́n nítorí ìtara tó ní fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti Júdà lọ́nà òdì.)