-
1 Tímótì 2:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Torí náà, mò ń pàrọwà fún yín ṣáájú ohun gbogbo pé kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀, kí ẹ máa gbàdúrà, kí ẹ máa dúpẹ́, kí ẹ sì máa bẹ̀bẹ̀ torí onírúurú èèyàn, 2 kí ẹ ṣe bẹ́ẹ̀ torí àwọn ọba àti gbogbo àwọn tó wà ní ipò gíga,*+ ká lè máa gbé ìgbé ayé tó pa rọ́rọ́ nìṣó pẹ̀lú ìbàlẹ̀ ọkàn, bí a ti ń fi gbogbo ọkàn wa sin Ọlọ́run, tí a sì ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan.+
-