Jeremáyà 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mi ò rán àwọn wòlíì náà, síbẹ̀ wọ́n sáré. Mi ò bá wọn sọ̀rọ̀, síbẹ̀ wọ́n sọ tẹ́lẹ̀.+ Jeremáyà 28:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Wòlíì Jeremáyà wá sọ fún wòlíì Hananáyà+ pé: “Jọ̀wọ́, fetí sílẹ̀, ìwọ Hananáyà! Jèhófà kò rán ọ, àmọ́ o ti mú kí àwọn èèyàn yìí gbẹ́kẹ̀ lé irọ́.+
15 Wòlíì Jeremáyà wá sọ fún wòlíì Hananáyà+ pé: “Jọ̀wọ́, fetí sílẹ̀, ìwọ Hananáyà! Jèhófà kò rán ọ, àmọ́ o ti mú kí àwọn èèyàn yìí gbẹ́kẹ̀ lé irọ́.+