-
Sáàmù 102:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi nígbà tí mo wà nínú wàhálà.+
-
-
Míkà 3:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ní àkókò yẹn, wọ́n á ké pe Jèhófà pé kó ran àwọn lọ́wọ́,
Àmọ́ kò ní dá wọn lóhùn.
-