Sáàmù 30:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìbínú rẹ̀ lórí èèyàn kì í pẹ́ rárá,+Àmọ́ ojú rere* rẹ̀ sí èèyàn wà títí ọjọ́ ayé.+ Ẹkún lè wà ní àṣálẹ́, àmọ́ tó bá di àárọ̀, igbe ayọ̀ á sọ.+
5 Nítorí ìbínú rẹ̀ lórí èèyàn kì í pẹ́ rárá,+Àmọ́ ojú rere* rẹ̀ sí èèyàn wà títí ọjọ́ ayé.+ Ẹkún lè wà ní àṣálẹ́, àmọ́ tó bá di àárọ̀, igbe ayọ̀ á sọ.+