Òwe 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹbọ ẹni burúkú jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+Àmọ́ àdúrà àwọn adúróṣinṣin máa ń múnú Rẹ̀ dùn.+