-
Diutarónómì 28:66, 67Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
66 Ẹ̀mí rẹ máa wà nínú ewu ńlá, ẹ̀rù á máa bà ọ́ tọ̀sántòru, kò sì ní dá ọ lójú pé wàá rí ìgbàlà. 67 Ní àárọ̀, wàá sọ pé, ‘Ì bá dáa ká ní alẹ́ la wà!’ tó bá sì di alẹ́, wàá sọ pé, ‘Ì bá dáa ká ní àárọ̀ la wà!’ nítorí ìpayà tó máa bá ọkàn rẹ àti nítorí ohun tí ojú rẹ máa rí.
-