-
2 Àwọn Ọba 21:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àmọ́, wọn kò ṣègbọràn, Mánásè sì ń ṣì wọ́n lọ́nà, ó ń mú kí wọ́n ṣe ohun tó burú ju ti àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà pa run kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
-