Émọ́sì 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Édómù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí ó fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,+Àti nítorí pé ó kọ̀ láti ṣàánú rẹ̀;Ó ń fi ìbínú rẹ̀ fà wọ́n ya láìdáwọ́ dúró,Kò sì yéé bínú sí wọn.+
11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Édómù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí ó fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,+Àti nítorí pé ó kọ̀ láti ṣàánú rẹ̀;Ó ń fi ìbínú rẹ̀ fà wọ́n ya láìdáwọ́ dúró,Kò sì yéé bínú sí wọn.+