Àìsáyà 65:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Wọn ò ní ṣiṣẹ́ kára* lásán,*+Wọn ò sì ní bímọ fún wàhálà,Torí àwọn ni ọmọ* tí wọ́n jẹ́ àwọn tí Jèhófà bù kún+Àti àwọn àtọmọdọ́mọ wọn pẹ̀lú wọn.+
23 Wọn ò ní ṣiṣẹ́ kára* lásán,*+Wọn ò sì ní bímọ fún wàhálà,Torí àwọn ni ọmọ* tí wọ́n jẹ́ àwọn tí Jèhófà bù kún+Àti àwọn àtọmọdọ́mọ wọn pẹ̀lú wọn.+