-
Àìsáyà 60:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Gbogbo èèyàn rẹ máa jẹ́ olódodo;
Ilẹ̀ náà máa di tiwọn títí láé.
-
-
Émọ́sì 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 ‘Màá gbìn wọ́n sórí ilẹ̀ wọn,
A kò sì ní fà wọ́n tu mọ́
Kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ wí.”
-