Ìsíkíẹ́lì 38:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘Èmi yóò mú kí idà kan dojú kọ ọ́ lórí gbogbo òkè mi,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Kálukú yóò fi idà rẹ̀ bá arákùnrin rẹ̀ jà.+
21 “‘Èmi yóò mú kí idà kan dojú kọ ọ́ lórí gbogbo òkè mi,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Kálukú yóò fi idà rẹ̀ bá arákùnrin rẹ̀ jà.+