-
Ìsíkíẹ́lì 39:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò yan ibì kan níbẹ̀ ní Ísírẹ́lì tí wọn yóò sin Gọ́ọ̀gù+ sí, ní àfonífojì tí àwọn tó ń rìnrìn àjò ní ìlà oòrùn òkun ń gbà kọjá, yóò sì dí ọ̀nà tí wọ́n ń gbà kọjá. Ibẹ̀ ni wọn yóò sin Gọ́ọ̀gù àti gbogbo èèyàn rẹ̀ tó pọ̀ rẹpẹtẹ sí, wọ́n á sì máa pe ibẹ̀ ní Àfonífojì Hamoni-Gọ́ọ̀gù.*+
-