ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 26:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 èmi náà yóò kẹ̀yìn sí yín, èmi fúnra mi yóò sì fìyà jẹ yín ní ìlọ́po méje torí ẹ̀ṣẹ̀ yín. 25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+

  • Diutarónómì 32:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),

      Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+

      Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+

      Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.

  • Sáàmù 106:40, 41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Torí náà, ìbínú Jèhófà ru sí àwọn èèyàn rẹ̀,

      Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kórìíra ogún rẹ̀.

      41 Léraléra ló fi wọ́n lé àwọn orílẹ̀-èdè lọ́wọ́,+

      Kí àwọn tó kórìíra wọn lè ṣàkóso lé wọn lórí.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́