Jeremáyà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 A ó dà wọ́n síta lábẹ́ oòrùn, òṣùpá àti lábẹ́ gbogbo ọmọ ogun ọ̀run tí wọ́n nífẹ̀ẹ́, tí wọ́n jọ́sìn, tí wọ́n tẹ̀ lé, tí wọ́n wá, tí wọ́n sì forí balẹ̀ fún.+ A ò ní kó wọn jọ, bẹ́ẹ̀ ni a ò ní sin wọ́n. Wọn á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀.”+
2 A ó dà wọ́n síta lábẹ́ oòrùn, òṣùpá àti lábẹ́ gbogbo ọmọ ogun ọ̀run tí wọ́n nífẹ̀ẹ́, tí wọ́n jọ́sìn, tí wọ́n tẹ̀ lé, tí wọ́n wá, tí wọ́n sì forí balẹ̀ fún.+ A ò ní kó wọn jọ, bẹ́ẹ̀ ni a ò ní sin wọ́n. Wọn á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀.”+