Ìsíkíẹ́lì 47:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn gba àárín Háúránì àti Damásíkù, títí lọ dé ẹ̀gbẹ́ Jọ́dánì láàárín Gílíádì+ àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì. Kí ẹ wọ̀n ọ́n láti ibi tí ààlà wà dé òkun ìlà oòrùn.* Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn nìyí.
18 “Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn gba àárín Háúránì àti Damásíkù, títí lọ dé ẹ̀gbẹ́ Jọ́dánì láàárín Gílíádì+ àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì. Kí ẹ wọ̀n ọ́n láti ibi tí ààlà wà dé òkun ìlà oòrùn.* Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn nìyí.