Jóṣúà 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ a ò ní fún àwọn ọmọ Léfì ní ìpín kankan láàárín yín,+ torí pé iṣẹ́ àlùfáà Jèhófà ni ogún wọn;+ Gádì, Rúbẹ́nì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ti gba ogún wọn lápá ìlà oòrùn Jọ́dánì, èyí tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún wọn.”
7 Àmọ́ a ò ní fún àwọn ọmọ Léfì ní ìpín kankan láàárín yín,+ torí pé iṣẹ́ àlùfáà Jèhófà ni ogún wọn;+ Gádì, Rúbẹ́nì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ti gba ogún wọn lápá ìlà oòrùn Jọ́dánì, èyí tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún wọn.”