45 “‘Nígbà tí ẹ bá pín ilẹ̀ náà bí ogún,+ kí ẹ mú ìpín kan tó jẹ́ mímọ́ lára ilẹ̀ náà wá fún Jèhófà láti fi ṣe ọrẹ.+ Kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́, kí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́.+ Gbogbo agbègbè rẹ̀ yóò jẹ́ mímọ́.