Àìsáyà 22:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní ọjọ́ yẹn, Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Máa ní kí wọ́n sunkún, kí wọ́n sì ṣọ̀fọ̀,+Ó máa ní kí wọ́n fá orí, kí wọ́n sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀.*
12 Ní ọjọ́ yẹn, Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Máa ní kí wọ́n sunkún, kí wọ́n sì ṣọ̀fọ̀,+Ó máa ní kí wọ́n fá orí, kí wọ́n sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀.*