Jẹ́nẹ́sísì 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ábúráhámù wá sún mọ́ ọn, ó sì sọ pé: “Ṣé o máa pa olódodo run pẹ̀lú ẹni burúkú+ ni? Ìsíkíẹ́lì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí mo ṣe sọ àsọtẹ́lẹ̀ náà tán, Pẹlatáyà ọmọ Bẹnáyà kú. Ni mo bá dojú bolẹ̀, mo sì ké jáde pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ṣé o máa pa àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì run ni?”+
13 Bí mo ṣe sọ àsọtẹ́lẹ̀ náà tán, Pẹlatáyà ọmọ Bẹnáyà kú. Ni mo bá dojú bolẹ̀, mo sì ké jáde pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ṣé o máa pa àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì run ni?”+