-
2 Àwọn Ọba 21:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Mánásè ta ẹ̀jẹ̀ àwọn aláìṣẹ̀ sílẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ débi pé ó kún Jerúsálẹ́mù láti ìkángun kan dé ìkángun kejì,+ yàtọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ èyí tí ó mú Júdà ṣẹ̀, tí wọ́n fi ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà.
-
-
Mátíù 23:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 ẹ sì sọ pé, ‘Ká ní a wà láyé nígbà ayé àwọn baba ńlá wa ni, a ò ní lọ́wọ́ sí bí wọ́n ṣe ta ẹ̀jẹ̀ àwọn wòlíì sílẹ̀.’
-