Sekaráyà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹsẹ̀ rẹ̀ yóò dúró sórí Òkè Ólífì,+ tó dojú kọ Jerúsálẹ́mù ní ìlà oòrùn; Òkè Ólífì yóò là sí méjì láti ìlà oòrùn* dé ìwọ̀ oòrùn,* àfonífojì ńlá kan yóò sì wà láàárín rẹ̀; ìdajì òkè náà yóò sún sí àríwá àti ìdajì sí gúúsù.
4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹsẹ̀ rẹ̀ yóò dúró sórí Òkè Ólífì,+ tó dojú kọ Jerúsálẹ́mù ní ìlà oòrùn; Òkè Ólífì yóò là sí méjì láti ìlà oòrùn* dé ìwọ̀ oòrùn,* àfonífojì ńlá kan yóò sì wà láàárín rẹ̀; ìdajì òkè náà yóò sún sí àríwá àti ìdajì sí gúúsù.