22 Èmi yóò rán àwọn ẹran inú igbó sáàárín yín,+ wọ́n á pa yín lọ́mọ jẹ,+ wọ́n á pa àwọn ẹran ọ̀sìn yín run, wọ́n á dín iye yín kù, àwọn ọ̀nà yín yóò sì dá páropáro.+
3 “‘Màá yan ìyọnu mẹ́rin lé wọn lórí,’*+ ni Jèhófà wí, ‘idà láti pa wọ́n, àwọn ajá láti wọ́ òkú wọn lọ àti àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run pẹ̀lú àwọn ẹranko orí ilẹ̀ láti jẹ wọ́n àti láti run wọ́n.+