-
Jeremáyà 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Kìkì pé kí o mọ ẹ̀bi rẹ lẹ́bi, nítorí o ti ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ. Ò ń bá àwọn àjèjì* lò pọ̀ lábẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀, àmọ́ o kò fetí sí ohùn mi,” ni Jèhófà wí.’”
-