ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 30:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wọ́n lọ sí Íjíbítì+ láì fọ̀rọ̀ lọ̀ mí,*+

      Láti wá ààbò lọ sọ́dọ̀ Fáráò,*

      Kí wọ́n sì fi òjìji Íjíbítì ṣe ibi ìsádi wọn!

       3 Àmọ́ ibi ààbò Fáráò máa dójú tì yín,

      Òjìji Íjíbítì tí ẹ sì fi ṣe ibi ìsádi máa rẹ̀ yín wálẹ̀.+

  • Jeremáyà 2:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Kí nìdí tí o fi fojú kékeré wo ọ̀nà rẹ tí kò gún?

      Ojú yóò tì ọ́ nítorí Íjíbítì,+

      Bí ojú ṣe tì ọ́ nítorí Ásíríà.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́