Jẹ́nẹ́sísì 38:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, ó yà sọ́dọ̀ rẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n bá ọ lò pọ̀,” ṣùgbọ́n kò mọ̀ pé ìyàwó ọmọ+ òun ni. Obìnrin náà bi í pé: “Kí lo máa fún mi tí o bá bá mi lò pọ̀?”
16 Torí náà, ó yà sọ́dọ̀ rẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n bá ọ lò pọ̀,” ṣùgbọ́n kò mọ̀ pé ìyàwó ọmọ+ òun ni. Obìnrin náà bi í pé: “Kí lo máa fún mi tí o bá bá mi lò pọ̀?”