-
Ìsíkíẹ́lì 23:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Èmi yóò bínú sí ọ, wọ́n á sì fi ìrunú bá ọ jà. Wọ́n á gé imú rẹ àti etí rẹ, idà ló sì máa pa àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú rẹ. Wọn yóò kó àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin lọ, iná sì máa run àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú rẹ.+
-