23 ‘Ó dájú pé màá sọ orúkọ ńlá mi di mímọ́,+ èyí tí wọ́n kó ẹ̀gàn bá láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí ẹ kẹ́gàn rẹ̀ láàárín wọn; àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘nígbà tí mo bá fi hàn lójú wọn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín yín.