Àìsáyà 66:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Wọ́n á jáde lọ, wọ́n á sì wo òkú àwọn tó ṣọ̀tẹ̀ sí mi;Torí ìdin ara wọn ò ní kú,Iná wọn ò ní kú,+Wọ́n á sì di ohun tó ń kóni nírìíra sí gbogbo èèyàn.”*
24 “Wọ́n á jáde lọ, wọ́n á sì wo òkú àwọn tó ṣọ̀tẹ̀ sí mi;Torí ìdin ara wọn ò ní kú,Iná wọn ò ní kú,+Wọ́n á sì di ohun tó ń kóni nírìíra sí gbogbo èèyàn.”*