Ìsíkíẹ́lì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó wá na ohun tó dà bí ọwọ́ jáde, ó fa irun orí mi, ẹ̀mí kan sì gbé mi nínú ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run lọ sí agbedeméjì ayé àti ọ̀run. Ó gbé mi wá sí Jerúsálẹ́mù, sí ẹnubodè inú,+ èyí tó kọjú sí àríwá, níbi tí ère* owú tó ń múni jowú wà.+
3 Ó wá na ohun tó dà bí ọwọ́ jáde, ó fa irun orí mi, ẹ̀mí kan sì gbé mi nínú ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run lọ sí agbedeméjì ayé àti ọ̀run. Ó gbé mi wá sí Jerúsálẹ́mù, sí ẹnubodè inú,+ èyí tó kọjú sí àríwá, níbi tí ère* owú tó ń múni jowú wà.+