-
Jeremáyà 23:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ní ti àwọn wòlíì:
Ọkàn mi bà jẹ́ nínú mi.
Gbogbo egungun mi ń gbọ̀n.
Mo dà bí ọkùnrin tó ti mutí yó
Àti bí ọkùnrin tí wáìnì ń pa,
Nítorí Jèhófà àti nítorí àwọn ọ̀rọ̀ mímọ́ rẹ̀.
-