Ìsíkíẹ́lì 24:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Banú jẹ́, àmọ́ má ṣe jẹ́ kó hàn síta, má tẹ̀ lé àṣà àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ òkú.+ Wé láwàní rẹ,+ kí o sì wọ bàtà rẹ.+ Má bo ẹnu* rẹ,+ má sì jẹ oúnjẹ tí àwọn ẹlòmíì bá gbé wá fún ọ.”*+
17 Banú jẹ́, àmọ́ má ṣe jẹ́ kó hàn síta, má tẹ̀ lé àṣà àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ òkú.+ Wé láwàní rẹ,+ kí o sì wọ bàtà rẹ.+ Má bo ẹnu* rẹ,+ má sì jẹ oúnjẹ tí àwọn ẹlòmíì bá gbé wá fún ọ.”*+