Léfítíkù 26:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú yín máa jẹrà sí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín+ torí ẹ̀ṣẹ̀ yín. Àní, wọn yóò jẹrà dà nù torí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá wọn.+ Ìsíkíẹ́lì 33:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ìwọ ọmọ èèyàn, sọ fún ilé Ísírẹ́lì pé, ‘O ti sọ pé: “Ọ̀tẹ̀ wa àti ẹ̀ṣẹ̀ wa ti dẹ́rù pa wá, ó ń mú kó rẹ̀ wá;+ báwo la ṣe máa wá wà láàyè?”’+
39 Àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú yín máa jẹrà sí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín+ torí ẹ̀ṣẹ̀ yín. Àní, wọn yóò jẹrà dà nù torí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá wọn.+
10 “Ìwọ ọmọ èèyàn, sọ fún ilé Ísírẹ́lì pé, ‘O ti sọ pé: “Ọ̀tẹ̀ wa àti ẹ̀ṣẹ̀ wa ti dẹ́rù pa wá, ó ń mú kó rẹ̀ wá;+ báwo la ṣe máa wá wà láàyè?”’+