Ìsíkíẹ́lì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹrin, ọdún ọgbọ̀n, nígbà tí mo wà lẹ́bàá odò Kébárì+ láàárín àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn,+ ọ̀run ṣí sílẹ̀, mo sì rí ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.
1 Ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹrin, ọdún ọgbọ̀n, nígbà tí mo wà lẹ́bàá odò Kébárì+ láàárín àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn,+ ọ̀run ṣí sílẹ̀, mo sì rí ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.