Àìsáyà 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí Damásíkù ni orí Síríà,Résínì sì ni orí Damásíkù. Kí ọdún márùndínláàádọ́rin (65) tó pé,Éfúrémù máa fọ́ túútúú, wọn ò sì ní jẹ́ èèyàn mọ́.+
8 Torí Damásíkù ni orí Síríà,Résínì sì ni orí Damásíkù. Kí ọdún márùndínláàádọ́rin (65) tó pé,Éfúrémù máa fọ́ túútúú, wọn ò sì ní jẹ́ èèyàn mọ́.+