Ìsíkíẹ́lì 27:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn tó ń gbé Sídónì àti Áfádì+ ló ń bá ọ tukọ̀. Ìwọ Tírè, àwọn èèyàn rẹ tó já fáfá ló ń bá ọ tukọ̀.+ 9 Àwọn ará Gébálì+ tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́* tí wọ́n sì já fáfá ló dí àwọn àlàfo ara ọkọ̀ rẹ.+ Gbogbo ọkọ̀ òkun àti àwọn atukọ̀ wọn wá bá ọ dòwò pọ̀.
8 Àwọn tó ń gbé Sídónì àti Áfádì+ ló ń bá ọ tukọ̀. Ìwọ Tírè, àwọn èèyàn rẹ tó já fáfá ló ń bá ọ tukọ̀.+ 9 Àwọn ará Gébálì+ tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́* tí wọ́n sì já fáfá ló dí àwọn àlàfo ara ọkọ̀ rẹ.+ Gbogbo ọkọ̀ òkun àti àwọn atukọ̀ wọn wá bá ọ dòwò pọ̀.