Ìsíkíẹ́lì 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “‘Ǹjẹ́ inú mi máa ń dùn sí ikú ẹni burúkú?’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kó yí ìwà rẹ̀ pa dà kó sì máa wà láàyè?’+ 1 Tímótì 2:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.
23 “‘Ǹjẹ́ inú mi máa ń dùn sí ikú ẹni burúkú?’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kó yí ìwà rẹ̀ pa dà kó sì máa wà láàyè?’+
3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.