-
Sáàmù 130:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kí Ísírẹ́lì máa dúró de Jèhófà,
Nítorí ìfẹ́ Jèhófà kì í yẹ̀,+
Ó sì ní agbára ńlá tó lè fi rani pa dà.
8 Yóò ra Ísírẹ́lì pa dà nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
-