28 Nebukadinésárì wá kéde pé: “Ẹ yin Ọlọ́run Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò,+ tó rán áńgẹ́lì rẹ̀, tó sì gba àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé e, wọ́n sì kọ̀ láti tẹ̀ lé àṣẹ ọba, wọ́n ṣe tán láti kú dípò kí wọ́n sin ọlọ́run míì yàtọ̀ sí Ọlọ́run wọn tàbí kí wọ́n jọ́sìn rẹ̀.+